#6  
20.05.2011, 19:13
  Awo Ifadahunsi Eniorisan
Awo Ifadahunsi Eniorisan
 
: 29.07.2008
:
: 188
() : 26
190 () 81

OFO'SE
( )


Esinsinki igbehun apaasan. Eera ki igbohun apegede.
Oromodie to ba ku ki igbohun asa. Ojo a ba fran bo Ifa inu agbara eje lobi is un.Binikeni ba pere mi lai dara, kemi lagbaja ma gbo, kieti mi di si won o. Ase.

OFO'SE
( )


A gun oke ode sore, bee ni emyin ti nsoro, ti e nfehinkunle s oju ona.
Aje aiye, Aje Orun, e o gbodo je gi erun.
Obo igi owo. Eran ki ijewe ose. Aje ki iba legi Ajeobale.
Nje mo leiyeoba. Keiyekeiye ma ba le mi o. Mo deiyeoba. Ase.

OFO'SE
( )


Ojo lOjo l Ojo e e bOjo nle osu lo posese posese e e kosu lona. Ase.

OFO'SE
( )


Alaake nigi ewon. Oro lo nida.
Ida ni ijIfa akoni, awon lo sa gede fOrunmila, eyiti iku atarun nleri re.
Orunmila ni; E ko le pa mi.
Nwon ni kini Orunmila gboju le.
O ni; Mo ti je iku tan, owo Iku ko le to mi.
O ni: Ori ti abahun fi apegede oun naa ni ifi isegun, kigede ti nwon naa semi lagbaja.
Yii ma sise ko ma ri mi gbe se o. Ase.


OFO'SE
( )


Aiya ki ifodo. Aiya ki ifolo. Aiya enu ona ki ifonile.
Kaiya mi ma ja mo. Keru ma ba mi mo o. Ase.


OFO'SE
( )


Bi a ba gbale gbata, akitan la iko o fun.
Omi ki iwon laiye lOrun ki baluwe ma mumi.
Ewe oriki lo ni ki nwon fise rere ji mi.
Tiletona la ifi ji ologbo.
Ki nwon fise rere ji mi o. Ase.


OFO'SE
( , )


Abisi Olu, ibi se mi, ibi were, ibi bawo.
Ibi se me. Ki ibi Iku o se mi loni.
Ki ibi ofo o se mi loni. Eyin lakesin meso kesin re si. Ase.

OFO'SE GELEFUN
( , )
* , !


Bo se adagun moi, Olueri, ba mka a lakaaki. B o se odo agbara,
Osun, ba m ka a l akaaki. Ntori emi o mohun oyin ifi is afara,
Ng o mohun odide ifi ise idi re, emi o mhum Iya mi ifi s odo t o dagbo alagbo were.
Alagbo of e, alagbo wo ya wo omo. Ori sa to romi tutu, tp s ipe agan.
Yemoja, ba mi de di agbo omo mi, k o mu, k o ki. Asoogun fun ni ma gbeje.
Ba mi de di agbo omo mi. Ko mu, ko ki. Agbo olo-inu.
Ki olo- inu maa se olomitutu temi. Agbo fawofawo.
Ki fawofawo maa se olomitutu timi. Agbo igbona.
Ki igbona maa se olomitutu temi. Ase.

Ofo'se . Ofo'se , , , .
__________________
Orisha marketplace!
11 () c: